Songtexte.com Drucklogo

Tonni Ani Songtext
von King Sunny Adé

Tonni Ani Songtext

Sunny ti dé
Efi yi ariwo pẹlu agbaja
Sunny Ade ti de o
Efi yi ariwo pẹlu agbaja
Aláṣẹ green sports ti de
Efi yi ariwo pẹlu agbaja

Mo shì gba rẹgbe green sports
Ka fi yi ariwo pẹlu agbaja
Bello Akinleye ti dé
Efi yi ariwo pẹlu agbaja
Michael Babalola ti dé o
Efi yi ariwo pẹlu agbaja

Fólórunsó òní ti dé
Efi yi ariwo pẹlu agbaja
Babatunde Alade ti dé
Efi yi ariwo pẹlu agbaja
Akinyẹle sijona gbé dé
Efi yi ariwo pẹlu agbaja


Akinola Akinrona ti dé
Efi yi ariwo pẹlu agbaja
Matthew Olojede ti dé
Efi yi ariwo pẹlu agbaja
Ashimiu oti gbe de
Efi yi ariwo pẹlu agbaja
Ademola Esho ti dé
Efi yi ariwo pẹlu agbaja

Ṣarafa ti dé
Efi yi ariwo pẹlu agbaja
A tún gbé dé
Ka fi yi ariwo pẹlu agbaja

Àṣe ni ṣe ra re ṣọ gbo
Àṣe ni ṣe ra re o
Àṣe ni ṣe ra re o
Green sports yi gode agba
Àṣe ni ṣe ra re o
Àṣe ni ṣe ra re o
Oga agba ti fi kan sọ f′ori sọle
Àṣe ni ṣe ra re o
Àṣe ni ṣe ra re o

Songtext kommentieren

Log dich ein um einen Eintrag zu schreiben.
Schreibe den ersten Kommentar!

Beliebte Songtexte
von King Sunny Adé

Quiz
Whitney Houston sang „I Will Always Love ...“?

Fans

»Tonni Ani« gefällt bisher niemandem.